Jags: 218.107k tweets talking about this in the last 24 hours


People talking about Jags: - god_hates_jags - JanceUKUH - Mr_JAGs - OluSamuelBGG - Mr_JAGs - Mr_JAGs - Mr_JAGs - InsideKaduna_ - fredliner009 - Mr_JAGs[...]
- Mr_JAGs - tolurex - tiwantiwa360 - Mr_JAGs - tiwantiwa360 - sannihussein - sannihussein - tolurex - GbenleMubarak - Mr_JAGs - Mr_JAGs

This Tag appearing in: Canada: ( Ottawa - Calgary - ).
Vietnam: ( Hanoi - Hai Phong - Can Tho - Da Nang - Ho Chi Minh City - Vietnam - ).
United States: ( Milwaukee - Pittsburgh - ).
Puerto Rico: ( Puerto Rico - ).
Popular tweets tagged with Jags:
Jags Jubril A. Gawat @Mr_JAGs🔁 #ThrowbackThursday

Ta l'ómo èèyàn pàtàkì yí?


loading...
JANCE @JanceUKUH🔁Jags D so tough nh nh nh nh
AFC Championship Med @god_hates_jags🔁 ヽ༼ຈل͜ຈ༽ノ Raise Your Bortles ヽ༼ຈل͜ຈ༽ノ #NFLPlayoffs
Jags Jubril A. Gawat @Mr_JAGs🔁 #YorubaQuiz

Ta l'ómo ògbóntarìgì adẹ́rinpòsónú yìí?

E jọ̀wọ́ ẹ ba wá ritiwiti rẹ 🙏 🙏


Jubril A. Gawat @Mr_JAGs🔁 @Mr_JAGs Ọte gbe wa loni
Olu' Samuel 🇳🇬 @OluSamuelBGG🔁@Mr_JAGs Ọte gbe wa loni
Jubril A. Gawat @Mr_JAGs🔁 Gbam! Aíyé tì o lé rárá!! twitter.com
Jubril A. Gawat @Mr_JAGs🔁Orúkọ àwọn ẹyẹ ní ilẹ̀ Yorùbá.

Ostrich = ògòǹgò
Turkey = tòlótòló
Duck = Pẹ́pẹ́yẹ
Owl = òwìwí

Ẹ jọ̀wọ́ ẹ ba wá ritiwiti rẹ si gbogbo ọmọ Yorùbá 🙏 🙏


Inside Kaduna @InsideKaduna_🔁 @Mr_JAGs @Abdulqadeeradam @InsideKaduna_ Àwọn ìró labi Nigeria Ltd. 😊 😊 😊 😊 😊
RIP Chiedu @fredliner009🔁@Mr_JAGs @Abdulqadeeradam @InsideKaduna_ Àwọn ìró labi Nigeria Ltd. 😊 😊 😊 😊 😊
Jubril A. Gawat @Mr_JAGs🔁

Ọmọbìnrin kàn ti ọjọ́ orí rẹ kò jù ọdún méjìlélógún lọ ti fún ẹ̀gbọ́n rẹ ni àrùn (Kidney) kàn ni orílè-èdè

girl in 20s donates kidney to sister❤️❤️❤️👏👏👏🇦🇪🇦🇪🇦🇪


Folowosele Tolulope @tolurex🔁Emi ko ro bẹ..
Jubril A. Gawat @Mr_JAGs🔁

Orúkọ àwọn ẹranko ní gẹ̀ẹ́sì àti èdè Yorùbá

Leopard = àmọ̀tẹ́kùn

Hyena = ìkookò

Ẹ jọ̀wọ́, e ba wa ritwiti (retweet) rẹ sì àwọn ọmọ Yorùbá.


Àwa l'amú ìgbòrò dùn @tiwantiwa360🔁Njé wón sì tún lo fún okòwò kòkó?
#Morounmubo @sannihussein🔁Emi ko ro bẹ.. twitter.com
Gbenle Mubarak @GbenleMubarak🔁Njé wón sì tún lo fún okòwò kòkó? twitter.com
Jubril A. Gawat @Mr_JAGs🔁Ǹjẹ́ ẹ mọ ìtàn "Cocoa House" ní ìlú Ibadan?

How well do you know about "Cocoa House" in Ibadan?

Cocoa house fi ìgbàkan jẹ́ ilé- alájà tí ó ga jùlọ ni ìlú Nàìjíríà. Owó kòkó ni won fi kọ́ Cocoa house ni ọdún 1965. Agbegbe Dugbe ni ó wa.

, kindly RT.


Jubril A. Gawat @Mr_JAGs🔁Ǹjẹ́ o mọ̀ orúkọ àwọn kòkòrò yí ni èdè Yorùbá?

Bee = Oyin

Wasp = agbón

Kindly RT till it gets to all Yorùbá tweeps on twitter05

Ngôi sao không hiệu lựcNgôi sao không hiệu lựcNgôi sao không hiệu lựcNgôi sao không hiệu lựcNgôi sao không hiệu lực